Native Bible

Numbers 3:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei.

Numbers 3:18 in English

Numbers 3:18 · Berean Standard Bible

These were the names of the sons of Gershon by their clans: Libni and Shimei.

Context

16Mose sì kà wọ́n gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa ti pa á láṣẹ fún un. 17Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Lefi: Gerṣoni, Kohati àti Merari. 18Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei. 19Àwọn ìdílé Kohati ni: Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli. 20Àwọn ìdílé Merari ni: Mahili àti Muṣi. Wọ̀nyí ni ìdílé Lefi gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.