Native Bible

Numbers 3:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ìdílé Merari ni: Mahili àti Muṣi. Wọ̀nyí ni ìdílé Lefi gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn.

Numbers 3:20 in English

Numbers 3:20 · Berean Standard Bible

And the sons of Merari by their clans were Mahli and Mushi. These were the clans of the Levites, according to their families.

Context

18Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei. 19Àwọn ìdílé Kohati ni: Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli. 20Àwọn ìdílé Merari ni: Mahili àti Muṣi. Wọ̀nyí ni ìdílé Lefi gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn. 21Ti Gerṣoni ni ìdílé Libni àti Ṣimei; àwọn ni ìdílé Gerṣoni. 22Iye àwọn ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọ́n jẹ́ oṣù kan ó lé, jẹ́ ẹgbàata ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ (7,500).

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.