Native Bible

Numbers 3:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ìdílé Kohati ni: Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli.

Numbers 3:19 in English

Numbers 3:19 · Berean Standard Bible

The sons of Kohath by their clans were Amram, Izhar, Hebron, and Uzziel.

Context

17Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Lefi: Gerṣoni, Kohati àti Merari. 18Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei. 19Àwọn ìdílé Kohati ni: Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli. 20Àwọn ìdílé Merari ni: Mahili àti Muṣi. Wọ̀nyí ni ìdílé Lefi gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn. 21Ti Gerṣoni ni ìdílé Libni àti Ṣimei; àwọn ni ìdílé Gerṣoni.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.