Numeri 3:17
Numbers 3:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Lefi: Gerṣoni, Kohati àti Merari.
Numbers 3:17 in English
Numbers 3:17 · Berean Standard Bible
These were the sons of Levi by name: Gershon, Kohath, and Merari.
Context
15“Ka àwọn ọmọ Lefi nípa ilé baba wọn àti ìdílé wọn kí o ka gbogbo ọmọkùnrin láti ọmọ oṣù kan sókè.” 16Mose sì kà wọ́n gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa ti pa á láṣẹ fún un. 17Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Lefi:
Gerṣoni, Kohati àti Merari. 18Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni:
Libni àti Ṣimei. 19Àwọn ìdílé Kohati ni:
Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.