Native Bible

Numbers 3:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Mose sì kà wọ́n gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa ti pa á láṣẹ fún un.

Numbers 3:16 in English

Numbers 3:16 · Berean Standard Bible

So Moses numbered them according to the word of the LORD, as he had been commanded.

Context

14Nígbà náà ni Olúwa sọ fún Mose ní aginjù Sinai pé, 15“Ka àwọn ọmọ Lefi nípa ilé baba wọn àti ìdílé wọn kí o ka gbogbo ọmọkùnrin láti ọmọ oṣù kan sókè.” 16Mose sì kà wọ́n gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa ti pa á láṣẹ fún un. 17Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Lefi: Gerṣoni, Kohati àti Merari. 18Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.