Numeri 3:22
Numbers 3:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Iye àwọn ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọ́n jẹ́ oṣù kan ó lé, jẹ́ ẹgbàata ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ (7,500).
Numbers 3:22 in English
Numbers 3:22 · Berean Standard Bible
The number of all the males a month old or more was 7,500.
Context
20Àwọn ìdílé Merari ni:
Mahili àti Muṣi.
Wọ̀nyí ni ìdílé Lefi gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn. 21Ti Gerṣoni ni ìdílé Libni àti Ṣimei; àwọn ni ìdílé Gerṣoni. 22Iye àwọn ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọ́n jẹ́ oṣù kan ó lé, jẹ́ ẹgbàata ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ (7,500). 23Àwọn ìdílé Gerṣoni yóò pa ibùdó sí ìhà ìwọ̀-oòrùn lẹ́yìn àgọ́. 24Olórí àwọn ìdílé Gerṣoni ni Eliasafu ọmọ Láélì.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.