Native Bible

Numbers 3:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olórí àwọn ìdílé Gerṣoni ni Eliasafu ọmọ Láélì.

Numbers 3:24 in English

Numbers 3:24 · Berean Standard Bible

and the leader of the families of the Gershonites was Eliasaph son of Lael.

Context

22Iye àwọn ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọ́n jẹ́ oṣù kan ó lé, jẹ́ ẹgbàata ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ (7,500). 23Àwọn ìdílé Gerṣoni yóò pa ibùdó sí ìhà ìwọ̀-oòrùn lẹ́yìn àgọ́. 24Olórí àwọn ìdílé Gerṣoni ni Eliasafu ọmọ Láélì. 25Iṣẹ́ àwọn ìdílé Gerṣoni nínú àgọ́ ìpàdé ni pé àwọn yóò máa tọ́jú àgọ́, ìbòrí àgọ́, aṣọ títa ẹnu-ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, 26aṣọ títa ti àgbàlá, aṣọ títa ti ẹnu-ọ̀nà àgbàlá tó yí àgọ́ àti pẹpẹ ká, àwọn okùn rẹ̀ àti gbogbo ohun tó jẹ mọ́ lílò wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.