Numeri 26:16
Numbers 26:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ti Osni, ìdílé Osni; ti Eri, ìdílé Eri;
Numbers 26:16 in English
Numbers 26:16 · Berean Standard Bible
the Oznite clan from Ozni, the Erite clan from Eri,
Context
14Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Simeoni, ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé igba (22,200) ọkùnrin. 15Àwọn ọmọ Gadi bí ìdílé wọn:
ti Sefoni, ìdílé Sefoni;
ti Haggi, ìdílé Haggi;
ti Ṣuni, ìdílé Ṣuni; 16ti Osni, ìdílé Osni;
ti Eri, ìdílé Eri; 17ti Arodi, ìdílé Arodi;
ti Areli, ìdílé Areli. 18Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Gadi tí iye wọn sì jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (40,500).
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.