Native Bible

Numbers 26:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Gadi bí ìdílé wọn: ti Sefoni, ìdílé Sefoni; ti Haggi, ìdílé Haggi; ti Ṣuni, ìdílé Ṣuni;

Numbers 26:15 in English

Numbers 26:15 · Berean Standard Bible

These were the descendants of Gad by their clans: The Zephonite clan from Zephon, the Haggite clan from Haggi, the Shunite clan from Shuni,

Context

13ti Sera, ìdílé Sera; tí Saulu, ìdílé Saulu. 14Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Simeoni, ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé igba (22,200) ọkùnrin. 15Àwọn ọmọ Gadi bí ìdílé wọn: ti Sefoni, ìdílé Sefoni; ti Haggi, ìdílé Haggi; ti Ṣuni, ìdílé Ṣuni; 16ti Osni, ìdílé Osni; ti Eri, ìdílé Eri; 17ti Arodi, ìdílé Arodi; ti Areli, ìdílé Areli.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.