Native Bible

Numbers 26:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ti Arodi, ìdílé Arodi; ti Areli, ìdílé Areli.

Numbers 26:17 in English

Numbers 26:17 · Berean Standard Bible

the Arodite clan from Arod,* and the Arelite clan from Areli.

Context

15Àwọn ọmọ Gadi bí ìdílé wọn: ti Sefoni, ìdílé Sefoni; ti Haggi, ìdílé Haggi; ti Ṣuni, ìdílé Ṣuni; 16ti Osni, ìdílé Osni; ti Eri, ìdílé Eri; 17ti Arodi, ìdílé Arodi; ti Areli, ìdílé Areli. 18Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Gadi tí iye wọn sì jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (40,500). 19Àwọn ọmọ Juda ni Eri àti Onani, ṣùgbọ́n Eri àti Onani kú ní ilẹ̀ Kenaani.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.