Numeri 26:18
Numbers 26:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Gadi tí iye wọn sì jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (40,500).
Numbers 26:18 in English
Numbers 26:18 · Berean Standard Bible
These were the clans of Gad, and their registration numbered 40,500.
Context
16ti Osni, ìdílé Osni;
ti Eri, ìdílé Eri; 17ti Arodi, ìdílé Arodi;
ti Areli, ìdílé Areli. 18Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Gadi tí iye wọn sì jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì ó lé lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (40,500). 19Àwọn ọmọ Juda ni Eri àti Onani, ṣùgbọ́n Eri àti Onani kú ní ilẹ̀ Kenaani. 20Àti àwọn ọmọ Juda gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn:
ti Ṣela, ìdílé Ṣela;
ti Peresi, ìdílé Peresi;
ti Sera, ìdílé Sera.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.