Native Bible

Numbers 26:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ti Sera, ìdílé Sera; tí Saulu, ìdílé Saulu.

Numbers 26:13 in English

Numbers 26:13 · Berean Standard Bible

the Zerahite clan from Zerah,* and the Shaulite clan from Shaul.

Context

11Àwọn ọmọ Kora, bí ó ti wù kí ó rí, wọn kò kú. 12Àwọn ọmọ ìran Simeoni bí ìdílé wọn: ti Nemueli, ìdílé Nemueli; ti Jamini, ìdílé Jamini; ti Jakini, ìdílé Jakini; 13ti Sera, ìdílé Sera; tí Saulu, ìdílé Saulu. 14Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Simeoni, ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé igba (22,200) ọkùnrin. 15Àwọn ọmọ Gadi bí ìdílé wọn: ti Sefoni, ìdílé Sefoni; ti Haggi, ìdílé Haggi; ti Ṣuni, ìdílé Ṣuni;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.