Numeri 26:14
Numbers 26:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Simeoni, ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé igba (22,200) ọkùnrin.
Numbers 26:14 in English
Numbers 26:14 · Berean Standard Bible
These were the clans of Simeon, and there were 22,200 men.
Context
12Àwọn ọmọ ìran Simeoni bí ìdílé wọn:
ti Nemueli, ìdílé Nemueli;
ti Jamini, ìdílé Jamini;
ti Jakini, ìdílé Jakini; 13ti Sera, ìdílé Sera;
tí Saulu, ìdílé Saulu. 14Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Simeoni, ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé igba (22,200) ọkùnrin. 15Àwọn ọmọ Gadi bí ìdílé wọn:
ti Sefoni, ìdílé Sefoni;
ti Haggi, ìdílé Haggi;
ti Ṣuni, ìdílé Ṣuni; 16ti Osni, ìdílé Osni;
ti Eri, ìdílé Eri;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.