Native Bible

Lamentations 3:63 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wò wọ́n! Ní jíjòkòó tàbí ní dídìde, wọ́n ń ṣẹlẹ́yà mi nínú orin wọn.

Lamentations 3:63 in English

Lamentations 3:63 · Berean Standard Bible

When they sit and when they rise, see how they mock me in song.

Context

61Olúwa ìwọ ti gbọ́ ẹ̀gàn wọn àti ìmọ̀ búburú wọn sí mi, 62ohun tí àwọn ọ̀tá mi ń sọ sí mi ní gbogbo ọjọ́. 63Wò wọ́n! Ní jíjòkòó tàbí ní dídìde, wọ́n ń ṣẹlẹ́yà mi nínú orin wọn. 64Olúwa san wọ́n lẹ́san ohun tí ó tọ́ sí wọn fún ohun tí ọwọ́ wọn ti ṣe. 65Fi ìbòjú bò wọ́n ní ọkàn, kí o sì fi wọ́n ré.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.