Native Bible

Lamentations 3:61 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa ìwọ ti gbọ́ ẹ̀gàn wọn àti ìmọ̀ búburú wọn sí mi,

Lamentations 3:61 in English

Lamentations 3:61 · Berean Standard Bible

O LORD, You have heard their insults, all their plots against me—

Context

59O ti rí i, Olúwa, búburú tí a ṣe sí mi. Gba ẹjọ́ mi ró! 60Ìwọ ti rí ọ̀gbun ẹ̀san wọn, gbogbo ìmọ̀ wọn sí mi. 61Olúwa ìwọ ti gbọ́ ẹ̀gàn wọn àti ìmọ̀ búburú wọn sí mi, 62ohun tí àwọn ọ̀tá mi ń sọ sí mi ní gbogbo ọjọ́. 63Wò wọ́n! Ní jíjòkòó tàbí ní dídìde, wọ́n ń ṣẹlẹ́yà mi nínú orin wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.