Native Bible

Lamentations 3:59 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

O ti rí i, Olúwa, búburú tí a ṣe sí mi. Gba ẹjọ́ mi ró!

Lamentations 3:59 in English

Lamentations 3:59 · Berean Standard Bible

You have seen, O LORD, the wrong done to me; vindicate my cause!

Context

57O wá tòsí nígbà tí mo ké pè ọ́, o sì wí pé, “Má ṣe bẹ̀rù.” 58Olúwa, ìwọ gba ẹjọ́ mi rò, o ra ẹ̀mí mi padà. 59O ti rí i, Olúwa, búburú tí a ṣe sí mi. Gba ẹjọ́ mi ró! 60Ìwọ ti rí ọ̀gbun ẹ̀san wọn, gbogbo ìmọ̀ wọn sí mi. 61Olúwa ìwọ ti gbọ́ ẹ̀gàn wọn àti ìmọ̀ búburú wọn sí mi,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.