Native Bible

Lamentations 3:58 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa, ìwọ gba ẹjọ́ mi rò, o ra ẹ̀mí mi padà.

Lamentations 3:58 in English

Lamentations 3:58 · Berean Standard Bible

You defend my cause, O Lord; You redeem my life.

Context

56Ìwọ gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi, “Má ṣe di etí rẹ sí igbe ẹ̀bẹ̀ mi fún ìtura.” 57O wá tòsí nígbà tí mo ké pè ọ́, o sì wí pé, “Má ṣe bẹ̀rù.” 58Olúwa, ìwọ gba ẹjọ́ mi rò, o ra ẹ̀mí mi padà. 59O ti rí i, Olúwa, búburú tí a ṣe sí mi. Gba ẹjọ́ mi ró! 60Ìwọ ti rí ọ̀gbun ẹ̀san wọn, gbogbo ìmọ̀ wọn sí mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.