Native Bible

Lamentations 3:60 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìwọ ti rí ọ̀gbun ẹ̀san wọn, gbogbo ìmọ̀ wọn sí mi.

Lamentations 3:60 in English

Lamentations 3:60 · Berean Standard Bible

You have seen all their malice, all their plots against me.

Context

58Olúwa, ìwọ gba ẹjọ́ mi rò, o ra ẹ̀mí mi padà. 59O ti rí i, Olúwa, búburú tí a ṣe sí mi. Gba ẹjọ́ mi ró! 60Ìwọ ti rí ọ̀gbun ẹ̀san wọn, gbogbo ìmọ̀ wọn sí mi. 61Olúwa ìwọ ti gbọ́ ẹ̀gàn wọn àti ìmọ̀ búburú wọn sí mi, 62ohun tí àwọn ọ̀tá mi ń sọ sí mi ní gbogbo ọjọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.