Ẹkún Jeremiah 3:62
Lamentations 3:62 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ohun tí àwọn ọ̀tá mi ń sọ sí mi ní gbogbo ọjọ́.
Lamentations 3:62 in English
Lamentations 3:62 · Berean Standard Bible
the slander and murmuring of my assailants against me all day long.
Context
60Ìwọ ti rí ọ̀gbun ẹ̀san wọn,
gbogbo ìmọ̀ wọn sí mi. 61Olúwa ìwọ ti gbọ́ ẹ̀gàn wọn
àti ìmọ̀ búburú wọn sí mi, 62ohun tí àwọn ọ̀tá mi ń sọ
sí mi ní gbogbo ọjọ́. 63Wò wọ́n! Ní jíjòkòó tàbí ní dídìde,
wọ́n ń ṣẹlẹ́yà mi nínú orin wọn. 64Olúwa san wọ́n lẹ́san ohun tí ó tọ́ sí wọn
fún ohun tí ọwọ́ wọn ti ṣe.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.