Ẹkún Jeremiah 3:64
Lamentations 3:64 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Olúwa san wọ́n lẹ́san ohun tí ó tọ́ sí wọn fún ohun tí ọwọ́ wọn ti ṣe.
Lamentations 3:64 in English
Lamentations 3:64 · Berean Standard Bible
You will pay them back what they deserve, O LORD, according to the work of their hands.
Context
62ohun tí àwọn ọ̀tá mi ń sọ
sí mi ní gbogbo ọjọ́. 63Wò wọ́n! Ní jíjòkòó tàbí ní dídìde,
wọ́n ń ṣẹlẹ́yà mi nínú orin wọn. 64Olúwa san wọ́n lẹ́san ohun tí ó tọ́ sí wọn
fún ohun tí ọwọ́ wọn ti ṣe. 65Fi ìbòjú bò wọ́n ní ọkàn,
kí o sì fi wọ́n ré. 66Ni wọ́n lára kí o sì pa wọ́n run pẹ̀lú ìbínú,
lábẹ́ ọ̀run Olúwa.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.