Native Bible

Lamentations 3:65 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Fi ìbòjú bò wọ́n ní ọkàn, kí o sì fi wọ́n ré.

Lamentations 3:65 in English

Lamentations 3:65 · Berean Standard Bible

Put a veil of anguish over their hearts; may Your curse be upon them!

Context

63Wò wọ́n! Ní jíjòkòó tàbí ní dídìde, wọ́n ń ṣẹlẹ́yà mi nínú orin wọn. 64Olúwa san wọ́n lẹ́san ohun tí ó tọ́ sí wọn fún ohun tí ọwọ́ wọn ti ṣe. 65Fi ìbòjú bò wọ́n ní ọkàn, kí o sì fi wọ́n ré. 66Ni wọ́n lára kí o sì pa wọ́n run pẹ̀lú ìbínú, lábẹ́ ọ̀run Olúwa.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.