Native Bible

Lamentations 3:48 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Omijé ń sàn ní ojú mi bí odò nítorí a pa àwọn ènìyàn mi run.

Lamentations 3:48 in English

Lamentations 3:48 · Berean Standard Bible

Streams of tears flow from my eyes over the destruction of the daughter of my people.

Context

46“Gbogbo àwọn ọ̀tá wa ti la ẹnu wọn gbòòrò sí wa. 47Àwa ti jìyà àti ìparun, nínú ìbẹ̀rù àti ewu.” 48Omijé ń sàn ní ojú mi bí odò nítorí a pa àwọn ènìyàn mi run. 49Ojú mi kò dá fún omijé, láì sinmi, 50títí ìgbà tí Olúwa yóò síjú wolẹ̀ láti òkè ọ̀run tí yóò sì rí i.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.