Native Bible

Lamentations 3:47 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwa ti jìyà àti ìparun, nínú ìbẹ̀rù àti ewu.”

Lamentations 3:47 in English

Lamentations 3:47 · Berean Standard Bible

Panic and pitfall have come upon us— devastation and destruction.

Context

45Ó ti sọ wá di èérí àti ààtàn láàrín orílẹ̀-èdè gbogbo. 46“Gbogbo àwọn ọ̀tá wa ti la ẹnu wọn gbòòrò sí wa. 47Àwa ti jìyà àti ìparun, nínú ìbẹ̀rù àti ewu.” 48Omijé ń sàn ní ojú mi bí odò nítorí a pa àwọn ènìyàn mi run. 49Ojú mi kò dá fún omijé, láì sinmi,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.