Native Bible

Lamentations 3:49 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ojú mi kò dá fún omijé, láì sinmi,

Lamentations 3:49 in English

Lamentations 3:49 · Berean Standard Bible

My eyes overflow unceasingly, without relief,

Context

47Àwa ti jìyà àti ìparun, nínú ìbẹ̀rù àti ewu.” 48Omijé ń sàn ní ojú mi bí odò nítorí a pa àwọn ènìyàn mi run. 49Ojú mi kò dá fún omijé, láì sinmi, 50títí ìgbà tí Olúwa yóò síjú wolẹ̀ láti òkè ọ̀run tí yóò sì rí i. 51Ohun tí mo rí mú ìbẹ̀rù wá ọkàn mi nítorí gbogbo àwọn obìnrin ìlú mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.