Native Bible

Lamentations 3:50 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

títí ìgbà tí Olúwa yóò síjú wolẹ̀ láti òkè ọ̀run tí yóò sì rí i.

Lamentations 3:50 in English

Lamentations 3:50 · Berean Standard Bible

until the LORD looks down from heaven and sees.

Context

48Omijé ń sàn ní ojú mi bí odò nítorí a pa àwọn ènìyàn mi run. 49Ojú mi kò dá fún omijé, láì sinmi, 50títí ìgbà tí Olúwa yóò síjú wolẹ̀ láti òkè ọ̀run tí yóò sì rí i. 51Ohun tí mo rí mú ìbẹ̀rù wá ọkàn mi nítorí gbogbo àwọn obìnrin ìlú mi. 52Àwọn tí ó jẹ́ ọ̀tá mi láìnídìí dẹ mí bí ẹyẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.