Ẹkún Jeremiah 3:52
Lamentations 3:52 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn tí ó jẹ́ ọ̀tá mi láìnídìí dẹ mí bí ẹyẹ.
Lamentations 3:52 in English
Lamentations 3:52 · Berean Standard Bible
Without cause my enemies hunted me like a bird.
Context
50títí ìgbà tí Olúwa yóò síjú wolẹ̀
láti òkè ọ̀run tí yóò sì rí i. 51Ohun tí mo rí mú ìbẹ̀rù wá ọkàn mi
nítorí gbogbo àwọn obìnrin ìlú mi. 52Àwọn tí ó jẹ́ ọ̀tá mi láìnídìí
dẹ mí bí ẹyẹ. 53Wọ́n gbìyànjú láti mú òpin dé bá ayé mi nínú ihò
wọ́n sì ju òkúta lù mí. 54Orí mi kún fún omi,
mo sì rò pé ìgbẹ̀yìn dé.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.