Native Bible

Lamentations 3:54 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Orí mi kún fún omi, mo sì rò pé ìgbẹ̀yìn dé.

Lamentations 3:54 in English

Lamentations 3:54 · Berean Standard Bible

The waters flowed over my head, and I thought I was going to die.

Context

52Àwọn tí ó jẹ́ ọ̀tá mi láìnídìí dẹ mí bí ẹyẹ. 53Wọ́n gbìyànjú láti mú òpin dé bá ayé mi nínú ihò wọ́n sì ju òkúta lù mí. 54Orí mi kún fún omi, mo sì rò pé ìgbẹ̀yìn dé. 55Mo pe orúkọ rẹ, Olúwa, láti ọ̀gbun ìsàlẹ̀ ihò. 56Ìwọ gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi, “Má ṣe di etí rẹ sí igbe ẹ̀bẹ̀ mi fún ìtura.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.