Native Bible

Lamentations 3:55 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Mo pe orúkọ rẹ, Olúwa, láti ọ̀gbun ìsàlẹ̀ ihò.

Lamentations 3:55 in English

Lamentations 3:55 · Berean Standard Bible

I called on Your name, O LORD, out of the depths of the Pit.

Context

53Wọ́n gbìyànjú láti mú òpin dé bá ayé mi nínú ihò wọ́n sì ju òkúta lù mí. 54Orí mi kún fún omi, mo sì rò pé ìgbẹ̀yìn dé. 55Mo pe orúkọ rẹ, Olúwa, láti ọ̀gbun ìsàlẹ̀ ihò. 56Ìwọ gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi, “Má ṣe di etí rẹ sí igbe ẹ̀bẹ̀ mi fún ìtura.” 57O wá tòsí nígbà tí mo ké pè ọ́, o sì wí pé, “Má ṣe bẹ̀rù.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.