Native Bible

Lamentations 3:46 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Gbogbo àwọn ọ̀tá wa ti la ẹnu wọn gbòòrò sí wa.

Lamentations 3:46 in English

Lamentations 3:46 · Berean Standard Bible

All our enemies open their mouths against us.

Context

44Ìwọ ti fi àwọsánmọ̀ bo ara rẹ pé kí àdúrà wa má ba à dé ọ̀dọ̀ rẹ. 45Ó ti sọ wá di èérí àti ààtàn láàrín orílẹ̀-èdè gbogbo. 46“Gbogbo àwọn ọ̀tá wa ti la ẹnu wọn gbòòrò sí wa. 47Àwa ti jìyà àti ìparun, nínú ìbẹ̀rù àti ewu.” 48Omijé ń sàn ní ojú mi bí odò nítorí a pa àwọn ènìyàn mi run.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.