Native Bible

Lamentations 3:44 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìwọ ti fi àwọsánmọ̀ bo ara rẹ pé kí àdúrà wa má ba à dé ọ̀dọ̀ rẹ.

Lamentations 3:44 in English

Lamentations 3:44 · Berean Standard Bible

You have covered Yourself with a cloud that no prayer can pass through.

Context

42“Àwa ti ṣẹ̀ a sì ti ṣọ̀tẹ̀ ìwọ kò sì fi ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá. 43“Ìwọ fi ìbínú bo ara rẹ ìwọ sì ń lépa wa; ìwọ ń parun láìsí àánú. 44Ìwọ ti fi àwọsánmọ̀ bo ara rẹ pé kí àdúrà wa má ba à dé ọ̀dọ̀ rẹ. 45Ó ti sọ wá di èérí àti ààtàn láàrín orílẹ̀-èdè gbogbo. 46“Gbogbo àwọn ọ̀tá wa ti la ẹnu wọn gbòòrò sí wa.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.