Native Bible

Lamentations 3:45 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó ti sọ wá di èérí àti ààtàn láàrín orílẹ̀-èdè gbogbo.

Lamentations 3:45 in English

Lamentations 3:45 · Berean Standard Bible

You have made us scum and refuse among the nations.

Context

43“Ìwọ fi ìbínú bo ara rẹ ìwọ sì ń lépa wa; ìwọ ń parun láìsí àánú. 44Ìwọ ti fi àwọsánmọ̀ bo ara rẹ pé kí àdúrà wa má ba à dé ọ̀dọ̀ rẹ. 45Ó ti sọ wá di èérí àti ààtàn láàrín orílẹ̀-èdè gbogbo. 46“Gbogbo àwọn ọ̀tá wa ti la ẹnu wọn gbòòrò sí wa. 47Àwa ti jìyà àti ìparun, nínú ìbẹ̀rù àti ewu.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.