Native Bible

Lamentations 3:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó dára fún ènìyàn láti gbé àjàgà nígbà tí ó wà ní èwe.

Lamentations 3:27 in English

Lamentations 3:27 · Berean Standard Bible

It is good for a man to bear the yoke while he is still young.

Context

25Dídára ni Olúwa fún àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ̀, sí àwọn tí ó ń wá a. 26Ó dára kí a ní sùúrù fún ìgbàlà Olúwa. 27Ó dára fún ènìyàn láti gbé àjàgà nígbà tí ó wà ní èwe. 28Jẹ́ kí ó jókòó ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́, nítorí Olúwa ti fi fún un. 29Jẹ́ kí ó bo ojú rẹ̀ sínú eruku— ìrètí sì lè wà.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.