Native Bible

Lamentations 3:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Dídára ni Olúwa fún àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ̀, sí àwọn tí ó ń wá a.

Lamentations 3:25 in English

Lamentations 3:25 · Berean Standard Bible

The LORD is good to those who wait for Him, to the soul who seeks Him.

Context

23Wọ́n jẹ́ ọ̀tún ní àárọ̀; títóbi ni òdodo rẹ̀. 24Mo wí fún ara mi, ìpín mi ni Olúwa; nítorí náà èmi yóò dúró dè ọ́. 25Dídára ni Olúwa fún àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ̀, sí àwọn tí ó ń wá a. 26Ó dára kí a ní sùúrù fún ìgbàlà Olúwa. 27Ó dára fún ènìyàn láti gbé àjàgà nígbà tí ó wà ní èwe.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.