Native Bible

Lamentations 3:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó dára kí a ní sùúrù fún ìgbàlà Olúwa.

Lamentations 3:26 in English

Lamentations 3:26 · Berean Standard Bible

It is good to wait quietly for the salvation of the LORD.

Context

24Mo wí fún ara mi, ìpín mi ni Olúwa; nítorí náà èmi yóò dúró dè ọ́. 25Dídára ni Olúwa fún àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ̀, sí àwọn tí ó ń wá a. 26Ó dára kí a ní sùúrù fún ìgbàlà Olúwa. 27Ó dára fún ènìyàn láti gbé àjàgà nígbà tí ó wà ní èwe. 28Jẹ́ kí ó jókòó ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́, nítorí Olúwa ti fi fún un.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.