Native Bible

Lamentations 3:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Jẹ́ kí ó jókòó ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́, nítorí Olúwa ti fi fún un.

Lamentations 3:28 in English

Lamentations 3:28 · Berean Standard Bible

Let him sit alone in silence, for God has disciplined him.

Context

26Ó dára kí a ní sùúrù fún ìgbàlà Olúwa. 27Ó dára fún ènìyàn láti gbé àjàgà nígbà tí ó wà ní èwe. 28Jẹ́ kí ó jókòó ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́, nítorí Olúwa ti fi fún un. 29Jẹ́ kí ó bo ojú rẹ̀ sínú eruku— ìrètí sì lè wà. 30Jẹ́ kí ó fi ẹ̀rẹ̀kẹ́ fún àwọn tí yóò gbá a, sì jẹ́ kí ó wà ní ìdójútì.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.