Native Bible

Lamentations 3:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Jẹ́ kí ó bo ojú rẹ̀ sínú eruku— ìrètí sì lè wà.

Lamentations 3:29 in English

Lamentations 3:29 · Berean Standard Bible

Let him bury his face in the dust— perhaps there is still hope.

Context

27Ó dára fún ènìyàn láti gbé àjàgà nígbà tí ó wà ní èwe. 28Jẹ́ kí ó jókòó ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́, nítorí Olúwa ti fi fún un. 29Jẹ́ kí ó bo ojú rẹ̀ sínú eruku— ìrètí sì lè wà. 30Jẹ́ kí ó fi ẹ̀rẹ̀kẹ́ fún àwọn tí yóò gbá a, sì jẹ́ kí ó wà ní ìdójútì. 31Ènìyàn kò di ìtanù lọ́dọ̀ Olúwa títí láé.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.