Ẹkún Jeremiah 3:31
Lamentations 3:31 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ènìyàn kò di ìtanù lọ́dọ̀ Olúwa títí láé.
Lamentations 3:31 in English
Lamentations 3:31 · Berean Standard Bible
For the Lord will not cast us off forever.
Context
29Jẹ́ kí ó bo ojú rẹ̀ sínú eruku—
ìrètí sì lè wà. 30Jẹ́ kí ó fi ẹ̀rẹ̀kẹ́ fún àwọn tí yóò gbá a,
sì jẹ́ kí ó wà ní ìdójútì. 31Ènìyàn kò di ìtanù
lọ́dọ̀ Olúwa títí láé. 32Lóòtítọ́ ó mú ìbànújẹ́ wá, yóò fi àánú hàn,
nítorí títóbi ni ìfẹ́ rẹ̀. 33Nítorí kò mọ̀ ọ́n mọ̀ mú ìpọ́njú wá
tàbí ìrora wá fún ọmọ ènìyàn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.