Native Bible

Lamentations 3:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Mo wí fún ara mi, ìpín mi ni Olúwa; nítorí náà èmi yóò dúró dè ọ́.

Lamentations 3:24 in English

Lamentations 3:24 · Berean Standard Bible

“The LORD is my portion,” says my soul, “therefore I will hope in Him.”

Context

22Nítorí ìfẹ́ Olúwa tí ó lágbára ni àwa kò fi ṣègbé, nítorí ti àánú rẹ kì í kùnà. 23Wọ́n jẹ́ ọ̀tún ní àárọ̀; títóbi ni òdodo rẹ̀. 24Mo wí fún ara mi, ìpín mi ni Olúwa; nítorí náà èmi yóò dúró dè ọ́. 25Dídára ni Olúwa fún àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ̀, sí àwọn tí ó ń wá a. 26Ó dára kí a ní sùúrù fún ìgbàlà Olúwa.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.