Native Bible

Lamentations 3:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọ́n jẹ́ ọ̀tún ní àárọ̀; títóbi ni òdodo rẹ̀.

Lamentations 3:23 in English

Lamentations 3:23 · Berean Standard Bible

They are new every morning; great is Your faithfulness!

Context

21Síbẹ̀, èyí ni mo ní ní ọkàn àti nítorí náà ní mo nírètí. 22Nítorí ìfẹ́ Olúwa tí ó lágbára ni àwa kò fi ṣègbé, nítorí ti àánú rẹ kì í kùnà. 23Wọ́n jẹ́ ọ̀tún ní àárọ̀; títóbi ni òdodo rẹ̀. 24Mo wí fún ara mi, ìpín mi ni Olúwa; nítorí náà èmi yóò dúró dè ọ́. 25Dídára ni Olúwa fún àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ̀, sí àwọn tí ó ń wá a.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.