Native Bible

Lamentations 3:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Síbẹ̀, èyí ni mo ní ní ọkàn àti nítorí náà ní mo nírètí.

Lamentations 3:21 in English

Lamentations 3:21 · Berean Standard Bible

Yet I call this to mind, and therefore I have hope:

Context

19Mo ṣe ìrántí ìpọ́njú àti ìdààmú mi, ìkorò àti ìbànújẹ́. 20Mo ṣèrántí wọn, ọkàn mi sì gbọgbẹ́ nínú mi. 21Síbẹ̀, èyí ni mo ní ní ọkàn àti nítorí náà ní mo nírètí. 22Nítorí ìfẹ́ Olúwa tí ó lágbára ni àwa kò fi ṣègbé, nítorí ti àánú rẹ kì í kùnà. 23Wọ́n jẹ́ ọ̀tún ní àárọ̀; títóbi ni òdodo rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.