Native Bible

Lamentations 3:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Mo ṣe ìrántí ìpọ́njú àti ìdààmú mi, ìkorò àti ìbànújẹ́.

Lamentations 3:19 in English

Lamentations 3:19 · Berean Standard Bible

Remember my affliction and wandering, the wormwood and the gall.

Context

17Mo ti jìnnà sí àlàáfíà; mo ti gbàgbé ohun tí àṣeyege ń ṣe. 18Nítorí náà mo wí pé, “Ògo mi ti lọ àti ìrètí mi nínú Olúwa.” 19Mo ṣe ìrántí ìpọ́njú àti ìdààmú mi, ìkorò àti ìbànújẹ́. 20Mo ṣèrántí wọn, ọkàn mi sì gbọgbẹ́ nínú mi. 21Síbẹ̀, èyí ni mo ní ní ọkàn àti nítorí náà ní mo nírètí.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.