Native Bible

Lamentations 3:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Mo ṣèrántí wọn, ọkàn mi sì gbọgbẹ́ nínú mi.

Lamentations 3:20 in English

Lamentations 3:20 · Berean Standard Bible

Surely my soul remembers and is humbled within me.

Context

18Nítorí náà mo wí pé, “Ògo mi ti lọ àti ìrètí mi nínú Olúwa.” 19Mo ṣe ìrántí ìpọ́njú àti ìdààmú mi, ìkorò àti ìbànújẹ́. 20Mo ṣèrántí wọn, ọkàn mi sì gbọgbẹ́ nínú mi. 21Síbẹ̀, èyí ni mo ní ní ọkàn àti nítorí náà ní mo nírètí. 22Nítorí ìfẹ́ Olúwa tí ó lágbára ni àwa kò fi ṣègbé, nítorí ti àánú rẹ kì í kùnà.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.