Native Bible

Lamentations 3:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Mo ti jìnnà sí àlàáfíà; mo ti gbàgbé ohun tí àṣeyege ń ṣe.

Lamentations 3:17 in English

Lamentations 3:17 · Berean Standard Bible

My soul has been deprived of peace; I have forgotten what prosperity is.

Context

15Ó ti kún mi pẹ̀lú ewé kíkorò àti ìdààmú bí omi. 16Ó ti fi òkúta kán eyín mi; ó ti tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ nínú eruku. 17Mo ti jìnnà sí àlàáfíà; mo ti gbàgbé ohun tí àṣeyege ń ṣe. 18Nítorí náà mo wí pé, “Ògo mi ti lọ àti ìrètí mi nínú Olúwa.” 19Mo ṣe ìrántí ìpọ́njú àti ìdààmú mi, ìkorò àti ìbànújẹ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.