Ẹkún Jeremiah 3:16
Lamentations 3:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó ti fi òkúta kán eyín mi; ó ti tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ nínú eruku.
Lamentations 3:16 in English
Lamentations 3:16 · Berean Standard Bible
He has ground my teeth with gravel and trampled me in the dust.
Context
14Mo di ẹni yẹ̀yẹ́ láàrín àwọn ènìyàn mi;
wọn yẹ̀yẹ́ mi pẹ̀lú orin ní gbogbo ọjọ́. 15Ó ti kún mi pẹ̀lú ewé kíkorò
àti ìdààmú bí omi. 16Ó ti fi òkúta kán eyín mi;
ó ti tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ nínú eruku. 17Mo ti jìnnà sí àlàáfíà;
mo ti gbàgbé ohun tí àṣeyege ń ṣe. 18Nítorí náà mo wí pé, “Ògo mi ti lọ
àti ìrètí mi nínú Olúwa.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.