Native Bible

Lamentations 3:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Mo di ẹni yẹ̀yẹ́ láàrín àwọn ènìyàn mi; wọn yẹ̀yẹ́ mi pẹ̀lú orin ní gbogbo ọjọ́.

Lamentations 3:14 in English

Lamentations 3:14 · Berean Standard Bible

I am a laughingstock to all my people; they mock me in song all day long.

Context

12Ó fa ọfà rẹ̀ yọ ó sì fi mí ṣe ohun ìtafàsí. 13Ó fa ọkàn mí ya pẹ̀lú ọfà nínú àkọ̀ rẹ̀. 14Mo di ẹni yẹ̀yẹ́ láàrín àwọn ènìyàn mi; wọn yẹ̀yẹ́ mi pẹ̀lú orin ní gbogbo ọjọ́. 15Ó ti kún mi pẹ̀lú ewé kíkorò àti ìdààmú bí omi. 16Ó ti fi òkúta kán eyín mi; ó ti tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ nínú eruku.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.