Native Bible

Lamentations 3:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó fa ọfà rẹ̀ yọ ó sì fi mí ṣe ohun ìtafàsí.

Lamentations 3:12 in English

Lamentations 3:12 · Berean Standard Bible

He bent His bow and set me as the target for His arrow.

Context

10Bí i beari tí ó dùbúlẹ̀, bí i kìnnìún tí ó sá pamọ́. 11Ó wọ́ mi kúrò ní ọ̀nà, ó tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ ó fi mi sílẹ̀ láìsí ìrànlọ́wọ́. 12Ó fa ọfà rẹ̀ yọ ó sì fi mí ṣe ohun ìtafàsí. 13Ó fa ọkàn mí ya pẹ̀lú ọfà nínú àkọ̀ rẹ̀. 14Mo di ẹni yẹ̀yẹ́ láàrín àwọn ènìyàn mi; wọn yẹ̀yẹ́ mi pẹ̀lú orin ní gbogbo ọjọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.