Native Bible

Lamentations 3:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó fa ọkàn mí ya pẹ̀lú ọfà nínú àkọ̀ rẹ̀.

Lamentations 3:13 in English

Lamentations 3:13 · Berean Standard Bible

He pierced my kidneys with His arrows.

Context

11Ó wọ́ mi kúrò ní ọ̀nà, ó tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ ó fi mi sílẹ̀ láìsí ìrànlọ́wọ́. 12Ó fa ọfà rẹ̀ yọ ó sì fi mí ṣe ohun ìtafàsí. 13Ó fa ọkàn mí ya pẹ̀lú ọfà nínú àkọ̀ rẹ̀. 14Mo di ẹni yẹ̀yẹ́ láàrín àwọn ènìyàn mi; wọn yẹ̀yẹ́ mi pẹ̀lú orin ní gbogbo ọjọ́. 15Ó ti kún mi pẹ̀lú ewé kíkorò àti ìdààmú bí omi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.