Native Bible

Lamentations 3:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó ti kún mi pẹ̀lú ewé kíkorò àti ìdààmú bí omi.

Lamentations 3:15 in English

Lamentations 3:15 · Berean Standard Bible

He has filled me with bitterness; He has intoxicated me with wormwood.

Context

13Ó fa ọkàn mí ya pẹ̀lú ọfà nínú àkọ̀ rẹ̀. 14Mo di ẹni yẹ̀yẹ́ láàrín àwọn ènìyàn mi; wọn yẹ̀yẹ́ mi pẹ̀lú orin ní gbogbo ọjọ́. 15Ó ti kún mi pẹ̀lú ewé kíkorò àti ìdààmú bí omi. 16Ó ti fi òkúta kán eyín mi; ó ti tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ nínú eruku. 17Mo ti jìnnà sí àlàáfíà; mo ti gbàgbé ohun tí àṣeyege ń ṣe.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.