Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

fún ilé ìṣọ́ gíga gíga àti àwọn odi ìdáàbòbò,

Isaiah 2:15 in English

Isaiah 2:15 · Berean Standard Bible

against every high tower, against every fortified wall,

Context

13nítorí gbogbo igi kedari Lebanoni, tó ga tó rìpó àti gbogbo óákù Baṣani, 14nítorí gbogbo òkè gíga ńlá ńlá àti àwọn òkè kéékèèké, 15fún ilé ìṣọ́ gíga gíga àti àwọn odi ìdáàbòbò, 16fún gbogbo ọkọ̀ àwọn oníṣòwò àwọn ọkọ̀ tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́. 17Ìgbéraga ènìyàn ni a ó tẹ̀ lórí ba a ó sì rẹ ìgbéraga ènìyàn sílẹ̀, Olúwa nìkan ṣoṣo ni a ó gbéga ní ọjọ́ náà,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.