Isaiah 2:17
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìgbéraga ènìyàn ni a ó tẹ̀ lórí ba a ó sì rẹ ìgbéraga ènìyàn sílẹ̀, Olúwa nìkan ṣoṣo ni a ó gbéga ní ọjọ́ náà,
Isaiah 2:17 in English
Isaiah 2:17 · Berean Standard Bible
So the pride of man will be brought low, and the loftiness of men will be humbled; the LORD alone will be exalted in that day,
Context
15fún ilé ìṣọ́ gíga gíga
àti àwọn odi ìdáàbòbò, 16fún gbogbo ọkọ̀ àwọn oníṣòwò
àwọn ọkọ̀ tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́. 17Ìgbéraga ènìyàn ni a ó tẹ̀ lórí ba
a ó sì rẹ ìgbéraga ènìyàn sílẹ̀,
Olúwa nìkan ṣoṣo ni a ó gbéga ní ọjọ́ náà, 18gbogbo ère òrìṣà yóò pòórá. 19Àwọn ènìyàn yóò sálọ sínú ihò àpáta
àti sínú ihò ilẹ̀
kúrò lọ́wọ́ ìpayà Olúwa
àti ògo ọláńlá rẹ̀,
nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.